Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rúùtù sì fèsì wí pé, “Kí èmi kí ó máa rí ojúrere láti ọ̀dọ̀ rẹ ṣíwájú sí i olúwa mi. Ìwọ ti tù mí nínú nípa sísọ ọ̀rọ̀ rere sí ìránṣẹ́-bìnrin rẹ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé èmi kò tó ọ̀kan nínú àwọn ìránṣẹ́-bìnrin rẹ.”

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:13 ni o tọ