Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bóásì sì fèsì wí pé, “Èmi ti gbọ́ gbogbo bí o ti ń ṣe sí ìyá ọkọ ọ̀ rẹ láti ìgbà tí ọkọ rẹ ti kú àti bí o ti ṣe fi baba àti ìyá rẹ àti ilẹ̀ rẹ sílẹ̀, tí o sì wá láti gbé láàárin àwọn ènìyàn tí ìwọ kò mọ̀ rí tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:11 ni o tọ