Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 9:15-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. ó ń pe àwọn tí ó ń kọjá lọ,tí wọn ń lọ tààrà ní ọ̀nà wọn.

16. “Jẹ́ kí gbogbo ẹni tí ó jẹ́ aláìlóye súnmọ́ bí!”Ni ó wí fún ẹni tí òye kù díẹ̀ ká à tó fún.

17. “Omi tí a jí mu dùnoúnjẹ tí a jẹ ní ìkọ̀kọ̀ a máa ládùn!”

18. Ṣùgbọ́n wọn ò funra pé àwọn òkú wà níbẹ̀,pé àwọn àlejò rẹ̀ wà ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀ isà òkú.

Ka pipe ipin Òwe 9