Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 31:29-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. “Ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbìnrin ní ń ṣe nǹkan ọlọ́láṣùgbọ́n ìwọ ju gbogbo wọn lọ”

30. Ojú dáradára a máa tan ni, ẹwà sì jẹ́ asánnítorí obìnrin tí ó bẹ̀rù Olúwa yẹ kí ó gba oríyìn

31. sì fún un ní èrè tí ó tọ́ sí ikí o sì jẹ́ kí iṣẹ́ rẹ̀ fún un ní ìyìn ní ẹnu ibòde ìlú.

Ka pipe ipin Òwe 31