Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 28:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́rọ̀ ènìyàn le è gbọ́n lójú ara rẹ̀ṣùgbọ́n talákà tí ó ní òye rí ìdí, rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 28

Wo Òwe 28:11 ni o tọ