Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 28:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé eṣùgbọ́n olódodo láyà bí i kìnnìún.

2. Nígbà tí orílẹ̀ èdè bá ní orí kunkun, àwọn ọba rẹ̀ a máa pọ̀ṣùgbọ́n olóye àti onímọ̀ a máa pa òfin mọ́

3. ọba tí ó ni àwọn talákà láradàbí àgbàrá òjò tí ó ń gbá gbogbo ẹ̀gbìn lọ.

Ka pipe ipin Òwe 28