Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 26:7-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Bí ẹsẹ̀ arọ tí ó ń mi dirodironi òwe lẹ́nu àṣiwèrè.

8. Bí ìgbà tí a so òkúta mọ́ okùn títani fífún aláìgbọ́n ní ọlá.

9. Bí ẹ̀gún èṣùṣú lọ́wọ́ ọ̀mùtíni òwe lẹ́nu aláìgbọ́n.

10. Bí tafàtafà ti ń ṣe ni léṣe lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kanni ẹni tí ó gba aṣiwèrè síṣẹ́ tàbí ẹni tí ń kọjá lọ.

Ka pipe ipin Òwe 26