Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 26:27-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Bí ènìyàn kan bá gbẹ́ kòtò, yóò ṣubú sínú rẹ̀.Bí ẹnikan bá ju òkúta, yóò padà sọ́dọ̀ òun tìkára rẹ̀.

28. Ahọ́n ẹ̀tàn máa ń kórìíra àwọn tí ó ṣe ní ìkà,ẹnu ìtànjẹ sì máa ń pani run.

Ka pipe ipin Òwe 26