Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 26:16-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Ọ̀lẹ gbọ́n ní ojú ara rẹ̀,ju ènìyàn méje tí wọ́n le è fún un ní ìdáhùn ọlọgbọ́n.

17. Bí ènìyàn tí ó di ajá ní etí múni ẹni tí ń kọjá lọ tí ó dá sí ọ̀rọ̀ ìjà tí kì í ṣe tirẹ̀.

18. Bí i asínwín ti ń juọfà àti ọfà tí ń ṣekú pani

19. ni ènìyàn tí ń tan aládùúgbò rẹ̀ jẹtí ó sì wí pé, “Àwàdà lásán ni mo ń ṣe.”

Ka pipe ipin Òwe 26