Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 26:12-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

12. Ǹjẹ́ o rí ènìyàn tí ó jẹ́ ọlọ́gbọ́n ní ojú ara rẹ̀?Ìrètí ń bẹ fún aláìgbọ́n ènìyàn jù ú lọ.

13. Ọ̀lẹ wí pé: “Kìnnìún wà lójú ọ̀nàkìnnìún búburú ń ké ní ojú ọ̀nà.”

14. Bí ilẹ̀kùn ti ń yí lórí ìsolẹ̀kùn rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni ọ̀lẹ ń yí lórí ibùsùn rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 26