Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 26:10-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Bí tafàtafà ti ń ṣe ni léṣe lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kanni ẹni tí ó gba aṣiwèrè síṣẹ́ tàbí ẹni tí ń kọjá lọ.

11. Bí ajá ti í padà sí èébì rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni aṣiwèrè tún ń hu ìwà òmùgọ̀ rẹ̀.

12. Ǹjẹ́ o rí ènìyàn tí ó jẹ́ ọlọ́gbọ́n ní ojú ara rẹ̀?Ìrètí ń bẹ fún aláìgbọ́n ènìyàn jù ú lọ.

13. Ọ̀lẹ wí pé: “Kìnnìún wà lójú ọ̀nàkìnnìún búburú ń ké ní ojú ọ̀nà.”

Ka pipe ipin Òwe 26