Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 23:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun,kíyèsí ohun tí ó wà níwájú rẹ gidigidi.

2. Ìwọ a sì fi ọ̀bẹ lé ara rẹ ní ọ̀fun,bí ìwọ bá jẹ́ òkúndùn ènìyàn.

3. Má ṣe fẹ́ oúnjẹ-dídùn rẹ̀:nítorí pé oúnjẹ ẹ̀tàn ni.

Ka pipe ipin Òwe 23