Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 22:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dẹtí rẹ sílẹ̀,kí o gbọ́ ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n,kí o sì fi àyà rẹ sí ẹ̀kọ́ mi.

Ka pipe ipin Òwe 22

Wo Òwe 22:17 ni o tọ