Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 19:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó já baba rẹ̀ lulẹ̀, tí ó sì lé ìyá rẹ̀ jádeó jẹ́ adójútini ọmọ.

Ka pipe ipin Òwe 19

Wo Òwe 19:26 ni o tọ