Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aya oníwà rere ni adé ọkọ rẹ̀ṣùgbọ́n aya adójútini dàbí ìgbà tí inú egungun rẹ̀ jẹrà.

Ka pipe ipin Òwe 12

Wo Òwe 12:4 ni o tọ