Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 1:30-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

30. Níwọ̀n bí wọn kò ti gbà ìmọ̀ràn mití wọ́n sì kẹ́gàn ìmọ̀ràn mi,

31. Wọn yóò jẹ èrè iṣẹ́ ọwọ́ wọnwọn yóò sì jèrè èso ètè wọn ní kíkún

32. Nítorí ìrìnkurìn àwọn aláìmọ́kan ni yóò pa wọ́nìkáwọ́-gbera aláìgbọ́n ni yóò pa á run;

33. Ṣùgbọ́n ẹnìkan tí ó bá fetí sí mi, yóò gbé láìléwuyóò sì wà nínú ìdẹ̀ra, láì sí ìbẹ̀rù ìpalára.”

Ka pipe ipin Òwe 1