Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Òwe 1:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn òwe ti Sólómónì, ọmọ Dáfídì, ọba Ísírẹ́lì.

2. Láti le ní ọgbọ́n àti ẹ̀kọ́Láti ní òye àwọn ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀

3. Láti ní ẹ̀kọ́ àti gbé ìgbé ayé ìkíyèsára,láti ṣe ohun tí ó tọ́, àti òdodo tí ó sì dára

Ka pipe ipin Òwe 1