Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 6:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdàbà mi, aláìlábàwọ́n mi, ọ̀kan ni,ọ̀kan ṣoṣo ọmọbìnrin ìyá rẹ,ààyò ẹyọkan ṣoṣo ẹni tí ó bí i.Àwọn obìnrin rí i wọ́n pè é ní alábùkún fúnÀwọn ayaba àti àwọn àlè gbé oríyìn fun-un

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 6

Wo Orin Sólómónì 6:9 ni o tọ