Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ṣọ̀kalẹ̀ lọ sí ibi ọgbà èso igiláti wo àwọn ẹ̀ka igi tuntun ní àfonífojì,láti rí i bí àjàrà rúwé,tàbí bí pómégíránéètì ti rúdìí.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 6

Wo Orin Sólómónì 6:11 ni o tọ