Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àdàbà mi wà nínú pàlàpálá òkúta,ní ibi ìkọ̀kọ̀ ní orí òkè gíga,fi ojú rẹ hàn mí,jẹ́ kí èmi gbọ́ ohùn rẹ;Nítorí tí ohùn rẹ dùn,tí ojú rẹ sì ní ẹwà.

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 2

Wo Orin Sólómónì 2:14 ni o tọ