Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má a jẹ ayé pẹ̀lú ìyàwó rẹ, ẹni tí o fẹ́ràn, ní gbogbo ọjọ́ ayé àìní ìtumọ̀ yí tí Ọlọ́run ti fi fún ọ lábẹ́ oòrùn—gbogbo ọjọ́ àìní ìtumọ̀ rẹ. Nítorí èyí ni ìpín tìrẹ ní ayé àti nínú iṣẹ́ wàhálà rẹ ní abẹ́ oòrun.

Ka pipe ipin Oníwàásù 9

Wo Oníwàásù 9:9 ni o tọ