Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti rí ohun mìíràn lábẹ́ oòrùnEré-ìje kì í ṣe fún ẹni tí ó yáratàbí ogun fún alágbárabẹ́ẹ̀ ni oúnjẹ kò wà fún ọlọ́gbọ́ntàbí ọrọ̀ fún ẹni tí ó ní òyetàbí ojú rere fún ẹni tí ó ní ìmọ̀;ṣùgbọ́n ìgbà àti èsì ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Oníwàásù 9

Wo Oníwàásù 9:11 ni o tọ