Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 7:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rí ohun tí ó korò ju ikú lọobìnrin tí ó jẹ́ ẹ̀bìtì,tí ọkàn rẹ̀ jẹ́ tàkútétí ọwọ́ rẹ̀ sì jẹ́ ẹ̀wọ̀n,ọkùnrin tí ó bá tẹ́ Ọlọ́run lọ́rùn yóò le è yọ sílẹ̀ṣùgbọ́n ẹlẹ́ṣẹ̀ kò le è bọ́ nínú tàkúté rẹ̀.

Ka pipe ipin Oníwàásù 7

Wo Oníwàásù 7:26 ni o tọ