Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ọ̀kan bá ṣubú lulẹ̀,ọ̀rẹ́ rẹ̀ le è ràn án lọ́wọ́ kí ó fàá sókè,ṣùgbọ́n ìyọnu ni fún ọkùnrin náà tí ó ṣubútí kò sì ní ẹni tí ó le è ràn-án lọ́wọ́!

Ka pipe ipin Oníwàásù 4

Wo Oníwàásù 4:10 ni o tọ