Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 2:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ẹni tí ó bá tẹ́ Ọlọ́run lọ́rùn ni Ọlọ́run yóò fún ni ọgbọ́n, ìmọ̀ àti ìdùnnú, ṣùgbọ́n fún ẹlẹ́ṣẹ̀, o fún-un ní iṣẹ́ láti ṣà àti láti kó ohun-ìní pamọ́ kí ó sì fi fún ẹni tí o tẹ Ọlọ́run lọ́rùn. Eléyìí pẹ̀lú, aṣán ni, ó dàbí ẹni a gbìyànjú àti mú.

Ka pipe ipin Oníwàásù 2

Wo Oníwàásù 2:26 ni o tọ