Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í ṣe wí pé Oníwàásù jẹ́ ọlọ́gbọ́n nìkan, ṣùgbọ́n ó tún kọ́ àwọn ènìyàn ní ìmọ̀. Ó rò ó dáradára ó sì ṣe àwárí, ó sì gbé ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ òwe kalẹ̀ lẹ́sẹẹsẹ.

Ka pipe ipin Oníwàásù 12

Wo Oníwàásù 12:9 ni o tọ