Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n igi Ólífì dá wọn lóhùn pé, ‘Èmi yóò ha fi òróró mi sílẹ̀ èyí tí a ń lò láti fi ọ̀wọ̀ fún àwọn ọlọ́run àti ènìyàn kí èmi sì wá ṣolórí àwọn igi?’

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:9 ni o tọ