Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:54 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ojú kan náà ni ó pe ẹni tí ó ru àpáta rẹ̀ pé, “Yára yọ idà rẹ kí o sì pa mí, kí wọn má ba à sọ pé, ‘Obìnrin ni ó pa á.’ ” Ọ̀dọ́mọkùnrin náà sì fi ọ̀kọ̀ gún-un ó sì kú.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:54 ni o tọ