Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilé ìṣọ́ kan tí ó ní agbára sì wà nínú ìlú náà. Gbogbo àwọn ènìyàn ìlú náà ọkùnrin àti obìnrin sá sínú ilé ìṣọ́ náà. Wọ́n ti ara wọn mọ́ ibẹ̀ wọ́n sì sá lọ sí inú àjà ilé ìṣọ́ náà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:51 ni o tọ