Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kó wọn lọ sí ilé baba rẹ̀ ní Ófírà, níbẹ̀ ní orí òkúta kan ṣoṣo ni ó ti pa àádọ́rin nínú àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn Jérú-Báálì, ṣùgbọ́n Jótamù, àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ Jérúb-Báálì, bọ́ yọ nítorí pé ó sá pamọ́.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:5 ni o tọ