Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kó àwọn ènìyàn rẹ̀, ó pín wọn sí ẹgbẹ́ mẹ́ta ó sì sá pamọ́ sí inú oko. Nígbà tí ó sì rí tí àwọn ènìyàn náà ń jáde kúrò nínú ìlú, ó dìde ó gbógun tì wọ́n.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:43 ni o tọ