Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gáálì ké ó ní, “Wòkè, àwọn ènìyàn ń tọ̀ wá bọ̀ láti agbede-méjì ilẹ̀ wá àti ẹ̀gbẹ́ kan n sì ń bọ̀ láti ìhà igi àwọn aláfọ̀ṣẹ tí ń jẹ́ óákù-Méónénímù.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:37 ni o tọ