Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gáálì ọmọ Ébédì dáhùn pé, “Ta ni Ábímélékì tàbí tani Ṣékémù tí àwa ó fi sìn ín? Ọmọ Jerubu-Báálì kọ́ ní ṣe tàbí Ṣébútì kọ́ ní igbá kejì rẹ̀? Ẹ má sin àwọn ará Hámórì baba àwọn ará Ṣékémù, Èéṣe tí a ó fi sin Ábímélékì?

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:28 ni o tọ