Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn tí Jótamù ti sọ èyí tan, ó sá àṣálà lọ sí Béérì, ó sì gbé níbẹ̀ nítorí ó bẹ̀rù arákùnrin rẹ̀ Ábímélékì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:21 ni o tọ