Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 9:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹbi gbogbo àwọn ará Ṣékémù léèrè, ‘Èwo ló sàn fún un yín, ṣé kí gbogbo àwọn àádọ́rin ọmọ Jérú-Báálì jọba lórí yín ni tàbí kí ẹnìkan ṣoṣo ṣe àkóso yín?’ Ṣùgbọ́n ẹ rántí pé ẹran ara yín àti ẹ̀jẹ̀ yín ni èmi ń ṣe.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 9

Wo Onídájọ́ 9:2 ni o tọ