Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 8:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì fi àwọn wúrà náà ṣe Éfódì èyí tí ó gbé kalẹ̀ ní Òfírà ìlú rẹ̀. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì sọ ara wọn di aṣẹ́wó nípa sínsìn ní ibẹ̀. Ó sì di ẹ̀ṣẹ̀ fún Gídíónì àti ìdílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:27 ni o tọ