Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣébà àti Ṣálímúnà dá Gídíónì lóhùn pé, “Wá pa wá fún raàrẹ, ‘Nítorí bí ènìyàn bá ti rí bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ yóò rí.’ ” Gídíónì bọ́ ṣíwájú ó sì pa wọ́n, ó sì mú ohun ọ̀sọ́ tí ó wà ní ọrùn àwọn ràkúnmí wọn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:21 ni o tọ