Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì bi Ṣébà àti Ṣálímúnà pé, “Irú ọkùnrin tí ẹ pa ní Tábórì, bá wo ni wọ́n ṣe rí?”“Àwọn ọkùnrin náà dàbí rẹ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dàbí ọmọ ọba,” ní ìdáhùn wọn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 8

Wo Onídájọ́ 8:18 ni o tọ