Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì sì kó àwọn ọkùnrin náà lọ sí ibi ìṣun omi. Níbẹ̀ ni Olúwa ti wí fún un pé, “Kí ó pín àwọn ènìyàn náà sí ọ̀nà méjì. Ya àwọn tí ó fi ahọ́n wọn lá omi bí ajá kúrò lára àwọn tí ó kúnlẹ̀ láti mu omi pẹ̀lú ọwọ́ wọn.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:5 ni o tọ