Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì àti àwọn ọgọ́rùn-ún ọkùnrin tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ dé òpin ibùdó àwọn ará Mídíánì ní nǹkan bí agogo méjìlá padà. Wọ́n fun fèrè wọn, wọ́n sì tún fọ́ àwọn ìkòkò tí ó wà ní ọwọ́ mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:19 ni o tọ