Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì dé sí àsìkò tí ọkùnrin kan bẹ̀rẹ̀ sí í rọ́ àlá tí ó lá sí ọ̀kan nínú àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀. Ó ní, “Mo lá àlá kan, nínú àlá náà mo rí àkàrà kan tó ṣe róbótó tí a fi Báálì ṣe ń yí wọ inú ibùdó àwọn ará Mídíánì, ó sì kọlu àgọ́ pẹ̀lú agbára ńlá débi wí pé àgọ́ náà dojú dé, ó sì ṣubú.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:13 ni o tọ