Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn a máa wá pẹ̀lú ohun ọ̀sìn wọn àti àwọn àgọ́ wọn, wọn a sì dàbí eṣú nítorí i púpọ̀ wọn. Ènìyàn kò sì lè ka iye àwọn ènìyàn náà bí ni àwọn ẹran ọ̀sìn, wọ́n pọ̀ débi pé wọn kò ṣe é kà ní iye, wọn a bo ilẹ̀ náà wọn a sì jẹ ẹ́ run.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:5 ni o tọ