Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbára àwọn ará Mídíánì sì pọ̀ púpọ̀ lórí àwọn Ísírẹ́lì, wọ́n sì hùwà ipá sí wọn, nítorí ìdí èyí, àwọn Ísírẹ́lì sá lọ sí àwọn orí òkè, wọ́n sì kọ́ àgọ́ fún ara wọn nínú ihò àpáta, àti nínú ọ̀gbun àti ní ibi agbára nínú àpáta.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:2 ni o tọ