Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gídíónì dáhùn pé, Alàgbà, bí Olúwa bá wà pẹ̀lú wa, kí ló dé tí gbogbo ìwọ̀nyí fi ń ṣẹlẹ̀ sí wa? Níbi gbogbo àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ tí àwọn baba wa ròyìn rẹ̀ fún wa nígbà tí wọ́n wí pé, “Olúwa kò ha mú wa gòkè láti ilẹ̀ Éjíbítì wá? Ṣùgbọ́n nísinsin yìí Olúwa ti kọ̀ wá sílẹ̀, ó sì ti fi wá lé àwọn ará Mídíánì lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 6

Wo Onídájọ́ 6:13 ni o tọ