Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 5:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Wọn kò ha ti rí wọn, wọn kò ha ti pín ìkógun bọ̀ fún olúkálùkù:ọmọbìnrin kan tàbí méjì fún ọkùnrin kan,fún Ṣísérà ìkógun aṣọ aláràbarà,ìkógun aṣọ aláràbarà àti ọlọ́nà,àwọn aṣọ ọlọ́nà iyebíye fún ọrùn mi,gbogbo wọn tí a kó ní ogun?’

Ka pipe ipin Onídájọ́ 5

Wo Onídájọ́ 5:30 ni o tọ