Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 5:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó na ọwọ́ rẹ̀ mú ìṣó àgọ́,ó fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú òòlù awọ gbẹ́nàgbẹ́nà.Ó kan Ṣísérà mọ́lẹ̀ pẹ̀lú òòlù ọwọ́ rẹ̀, ó fọ́ ọ ní orí,Ó kàn ẹ̀bátí rẹ̀ mọ́lẹ̀ sinsiǹ.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 5

Wo Onídájọ́ 5:26 ni o tọ