Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gílíádì jókòó ní òkè odò Jọ́dánì.Èéṣe tí Dánì fi jókòó nínú ọkọ̀ ojú omi?Ásérì jòkòó ní etí bèbè òkun,ó sì n gbé èbúté rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 5

Wo Onídájọ́ 5:17 ni o tọ