Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dèbórà dá a lóhùn pé, “ó dára, èmi yóò bá ọ lọ ṣùgbọ́n ọlá ìṣẹ́gun tí o ń lọ yìí kò ní jẹ́ tìrẹ, nítorí Olúwa yóò fi Sísérà lé obìnrin lọ́wọ́” Báyìí Dèbórà bá Bárákì lọ sí Kédésì.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 4

Wo Onídájọ́ 4:9 ni o tọ