Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 4:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jáélì sì jáde síta láti pàdé Sísérà, ó sì wí fún-un pé, “Wọlé sínú àgọ́ mi, Olúwa mi, wọlé wá má ṣe bẹ̀rù nítorí pé ààbò ń bẹ fún ọ.” Ó sì yà sínú àgọ́ rẹ̀, ó sì fi aṣọ bò ó.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 4

Wo Onídájọ́ 4:18 ni o tọ