Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àsìkò yìí Hébérì, ọ̀kan nínú ẹ̀yà Kẹ́nì, ti ya ara rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn ẹ̀yà Kénì, òun sì ń gbé ibòmíràn títí dé ibi igi óákù Ṣánanímù, tí ó wà ni agbégbé Kédésì (àwọn ẹ̀yà Kénì jẹ́ ìran Hóbábù ẹni tí i ṣe àna Móṣè).

Ka pipe ipin Onídájọ́ 4

Wo Onídájọ́ 4:11 ni o tọ